Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde

Celková doba trvání:10 h 57 min
Yoruba Cosmology and the UFO Question
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
23:06
72. Oju baba ara; awon bi oju; asoro da bi agba
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
17:36
71. Ohun ti ko to okoo ki i je agba niya
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
12:11
70. Ofin ni yo so ara e; iyawo ti nna omo iyale
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
13:29
69. O ye eni gbogbo ko so pe isu o jina, ko ye alubata
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
14:18
68. "O ru ládugbó ò nrerá; kí ni ká so féni tó ru Òrìsà-a Yemoja?"
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
13:10
67. "Ó bó lówó iyò, ó dòbu."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
23:55
66. "Níbo lo forúko sí tí ò njé Làmbòròkí?"
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
10:55
65. "“Mo mò-ó gún, mo mò-ó tè,” niyán ewùrà-á fi nlémo."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
15:00
64. "Mélòó l’èjìgbò tí òkan è njé Ayé-gbogbo?"
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
14:10
63. "Lásán kó là n dé etù; ó ní eni tórí è mbá etù mu."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
16:13
62. "Kò-sí-nílé kì í jagun enu tì."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
15:21
61. "Kò sí mi lájo àjo ò kún: ara è ló tàn je."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
15:48
60. "Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?”"
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
13:00
59. "Kíni ànfàní-i kètèkètè lára kétékété à-gùn-fesè-wólè?"
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
09:41
58. "Kàkà kí kìnìún se akápò ekùn, olóde a mú ode è se."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
12:55
57. "Ká ríni lóde ò dàbí-i ká báni délé."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
16:56
56. "Ibi tí a fi iyò sí ló nsomi sí."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
10:21
55. "ìrùkèrè kì í yan ifá lódì; oge, dúró o kí mi."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
20:24
54. "Ìpàkó onípàkó là nrí; enieléni ní nrí teni."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
14:35
53. "Ilé-ni-mo-wà kì í jèbi ejó."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
14:11
52. "Igúnnugún bà lé òrùlé; ojú tó ilé ó tó oko."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
16:06
51. "Ibi tí a ti npìtàn ká tó jogún, ká mò pé ogún ibè ò kanni."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
15:03
50. "Gbogbo òrò ní nsojú èké."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
12:42
49: "Gbogbo egbé nje Má-yè-lóyè, ò nje Sáré-pegbé."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
15:05
48. "Eye tó fi ara wé igún, èhìn àdìrò ní nsùn."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
20:17
47: "Eran kí la ò je rí? Òpóló báni lábàtà ó ba búrúbúrú."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
14:02
46: "Eni tí a ò fé nílùú kì í jó lójú agbo."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
15:27
45: "Eni tí a gbé gun elédè, ìwòn ni kó yò mo; eni tó gesin, ilè ló mbò."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
17:35
44: "Ení dádé ti kúrò lómodé."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
18:09
43: "Egbé eni là ngúnyán ewùrà dè."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
23:36
42: "Èèyàn bí òbo lòbo nya láso."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
13:01
41: "Èsúrú se fújà ó té lówó oníyán..."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
22:44
40: "Eégún wolé, ó ní òun ò rí Ejonto; Ejontó ní, “Àkísà ni, àbí kíní wolé?""
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
16:38
39: "Dìgbòlugi-dìgbòlùùyàn, kò jé ká mo ajá tòótó."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
32:32
38: "Bí ojó ewúré ba pé, a ní kò sí ohun tí alápatàá lè fi òun se."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
18:43
37: "Bí olóde ò kú, òdee rè kì í hu gbégi."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
19:59
36: "Bí ojú bá rí, enu a dáké."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
15:02
35: "Bí kò sí tòbùn èèyàn, ta ni ìbá jí lówùúrò tí kó bójú sásá?"
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
16:07
34: "Bí elébo ò bá peni, àsefín ò yeni."
Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
17:05